Education resource centre


YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍDownload 0.79 Mb.
Page25/49
Date08.07.2018
Size0.79 Mb.
1   ...   21   22   23   24   25   26   27   28   ...   49

YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1

ÀŚÀ: Êkö Ilé

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríkì êkö ilé

 2. Ìkíni ní oríśiríśi ônà

d. Iśë ilé śíśe

e. Ìbõwõ fágbà

ç. Ìmötótó

f. Ìbömôwí abblOLÙKÖ:

 1. sô oríkì êkö ilé

 2. śàlàyé ní kíkún lórí oríśiríśi êkö ilé àti pàtàkì wôn láwùjô

d. śàlàyé ìkíni lóríśiríśi õnà

e. śàlàyé oríśiríśi õnà tí à ń gbà töjú ilé

ç. kô àwôn õrõ tó súyô sójú pátákó

AKËKÕÖ:


 1. Tëtí sí àlàyé olùkö

 2. Śe àfihàn ìkíni lóríśiríśi õnà, ìwà ômôlúàbí, ìtöjú ilé.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ìkõwé

 • Àwòrán

 • Téèpù

 • Tçlifísàn/ Rédíò

 • Fíìmù

2.

LÍTÍRÈŚÕ:

Ìwé Kíkà: Ìtàn Àròsô Ôlörõ GeereÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Kókó Õrõ

 2. Àhunpõ Ìtàn

d. Ôgbön ìsõtàn

e. Ibùdó ìtàn

ç. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá

f. Lílo èdè

g. Ìjçyô àśà

gb. Àmúyç àti àléébùOLÙKÖ:

 1. jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere

 2. śàlàyé kíkún lórí kókó àkóónú iśë bí ó ti jçyô nínú ìtàn àròsô.

 1. ìsônísókí àhunpõ ìtàn

 2. êdá ìtàn

 3. ôgbön ìsõtàn

 4. ìwúlò èdè

 5. ìjçyô õrõ

 6. àmúyç àti àléébù

 7. kô àwôn õrõ tí ó súyô sí ojú pátákó

AKËKÕÖ:

a. Ka ìwé

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Kô àwôn õrõ tó súyô pêlú ìtumõ wônOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ìkõwé

 • Ìwé ìtàn àròsô tí a yàn

3.

ÈDÈ: Álífábëtì Èdè Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Álífábëtì:

a, b, d, e, ç, f, g, gb, h, i, j, k, l, m, n, o, ô, p, r, s, ś, t, u, w, y

 1. Köńsónáýtì:

b, d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, ś, t, w, y

d. Fáwëlì: a, e, ç, i, o, ô, u
OLÙKÖ:

 1. kô álífábëtì yorùbá lápapõ sára pátáko fún akëkõö

 2. kô àwôn lëtà tí ó dúró fún ìró köńsónáýtì àti ìró fáwëlì

d. pe wön lökõõkan fún akëkõö.

AKËKÕÖ:

 1. fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà.

 2. pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà bí olùkö ti pè wön

d. śe àdàkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì àti fáwëlì naa

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. kádíböõdù ńlá tí a kô álífábëtì Yorùbá sí.

 2. kádíböõdù ńlá tí ó ń śe àfihàn àwôn ìró Köńsónáýtì àti fáwëlì lötõõtõ.

 3. káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà náà sí.

4.

ÀŚÀ: Àwôn oúnjç ilê Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríkì oúnjç

b. Oríśiríśi oúnjç

d. bí a śe ń śe oúnjç kõõkan

e. ìpín sí ìsõrí àwôn oúnjç ilê Yorùbá bí i: sêmíró, ôlöràá, afáralókun, amáradán abbl

ç. ìtöjú oúnjç àjçsëkù

f. àfiwé oúnjç àtijö àti ti òde òní.

g. oúnjç tí ìlú/ agbègbè kõõkan fërànOLÙKÖ:

 1. sô oríkì oúnjç

 2. sô oríśìí oúnjç

d. śàlàyé bí a śe ń śe oúnjç kõõkan

e. kô àwôn oúnjç tí ó bö sí ìsõrí kan náà sára pátákó

ç. sô bí a śe ń śe ìtöjú oúnjç tí ó bá sëkù

f. sõrõ lórí àýfààní oúnjç láti oko àti ewu oúnjç inú agolo

g. Ya àtç oúnjç ti ìlú/ agbègbè kõõkan fëràn sórí pátákó.

AKËKÕÖ:


 1. Tëtí sí àlàyé olùkö

 2. Sô èrò tiwôn lórí oúnjç

d. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.

e. Ya àtç tí olùkö yà sójú pátákó.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. Oríśìíríśìí oúnjç tútù

 2. Àwòrán

 3. Ohun èlò oúnjç:

  • Ìkòkò, epo, iyõ irú, ewébê, sítóófù abbl

5.

ÈDÈ: Sílébù èdè Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríkì sílébù

 2. Ìhun sílébù [F, KF, N]

d. pínpín õrõ sí sílébù

OLÙKÖ:

 1. sô oríkì sílébù

 2. śàlàyé ìhun sílébù

d. śe õpõlôpõ àpççrç pínpín õrõ sí sílébù sójú pátákó

AKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí àlàyé olùkö

 2. Śe àpççrç pínpín õrõ sí sílébù fúnra rê

d. kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. pátákó ìkõwé

 2. kádíböõdù tí ó śe àfihàn àwôn õrõ oní sílébù méjì, mëta abbl

6.

LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ èdè Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríkì lítírèśõ

 2. Êka lítírèśõ èdè Yorùbá

 1. Alohùn

 2. Àpilêkô

d. Àwôn ohun tí a lè fi dá ewì kõõkan mõ: sísun, dídá, kíkô, pípa, pípè

e. Ìlò èdè inú ewìOLÙKÖ:

 1. śe àlàyé àwôn àbùdá pàtàkì lítírèśõ

 2. śe àfiwé lítírèśõ àpilêkô àti alohùn

 3. kô àpççrç lítírèśõ àpilêkô fún àwôn akëkõö.

 4. śàlàyé àwôn ìsõrí mëtêêta lítírèśõ àpilêkõ láti fi ìyàtõ wön hàn.

 5. sô àpççrç õkõõkan àwôn ìsõrí náà fún akëkõö.

AKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí gbogbo àlàyé olùkö dáradára

 2. Ya àtç láti fi ìyàtõ lítírèśõ àpilêkô àti alohùn hàn.

 3. kô àpççrç mìíràn fún ìsõrí kõõkan lítírèśõ àpilêkô.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

Ìwé oríśiríśi

Lítírèśõ àpilêkô: eré-oníśe, ewì àti ìtàn àròsô


7.

LÍTÍRÈŚÕ: Ìtúpalê ewì alohùn (Àsàyàn ìwé kan)

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àkóónú

kókó õrõ àśà tó súyô

ìhun


lílé/ gbígbè, àdákô, àjùmõkô

ìlò èdè: ônà èdè àti ìsôwölo-èdè

ìjçyô àśà

b. Lítírèśõ alohùn mìíràn

d. õgangan ipò àwôn akéwì: êśìn wön/ ìśe wôn, àkókò ìkéwì abbl


OLÙKÖ:

jë kí akëkõö ka ewì alohùn löpõlöpõ ìgbà

śe àlàyé lórí kókó õrõ êkö, ìlò èdè, àmúyç àti àléébù inú ìwé àsàyàn ewì alohùn.

AKËKÕÖ:

fi etí sí ewì tí olùkö ń kà fún wôn.

Gbìyànjú láti kéwì tí ó bá mõ

d. ka ìwé àsàyàn yìíOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

Ìwé tó jçmö ewì alohùn

Àwòrán tó bá ewì yìí mu

Pátákó ìkõwé8.

ÌHUN ÕRÕ:

a. Möfíìmù ní èdè Yorùbá

b. Õnà tí a ń gbà śêdá õrõ-orúkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

oríkì möfíìmù

ìśêdá õrõ-orúkô –àfòmö ìbêrê (a-, on-, o, oní-, àì-, àti-, àfòmö àárin àpètúnpè (kíkún, çlëbç)


OLÙKÖ:

  1. Śàlàyé oríśìí ìhun õrõ

  2. Śàlàyé ìśêdá àwôn õrõ

d. Kô õpõlôpõ àpççrç oríśiríśi õrõ sórí pátákó.

AKËKÕÖ:

 1. Sô oríśiríśi ìhun õrõ

 2. Sô bí a śe śêdá àwôn õrõ

d. Da õrõ-orúkô ìśêdá tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. Śe àlàyé ìlò àfòmö ìbêrê onísílébù méjì láti śêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.

 2. Kô õrõ ìpìlê mëta sílê

d. Kô àpççrç õrõ ìśêdá alápètúnpè kíkún mëta àti alápètúnpè çlëbç

9.

IŚË ABÍNIBÍ

i. Onírúurú iśë ilê Yorùbá bí i àgbê, alágbêdç, onídìrí, aśô híhun, aró dídá, awakõ abbl

ii. Ìkíni àti ìdáhùn fún onírúurú iśë.

ÀKÓÓNÚ IŚË


 1. oríkì iśë abínibí àti àpççrç iśë: àgbê, ôdç, aśô híhun, aró dídá, epo fífõ, irun dídì, àyàn, olóólà, alágbêdç

 2. Bí a ti ń kö iśë

d. ìwúlò iśë kíkö

e. iśë ôkùnrin, obìnrin, tôkùnrin-tobìnrin ní àtijö àti lóde òní.OLÙKÖ:

 1. Sô oríkì àti ohun tí iśë abínibí jë

 2. Tö akëkõö sönà láti mô pàtàkì iśë śíśe àti bí a śe ń kö iśë kõõkan.

d. Sô àýfààní iśë kíkö

e. Kô ìjôra àti ìyàtõ tó wà nínú iśë abínibí àti tòde òní sójú pátákóAKËKÕÖ:

 1. Sô ohun tí o mõ nípa iśë śíśe àti ìdí tí ó fi yç kí ènìyàn śiśë

 2. Kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé rç.

d. Śe àfiwé iśë abínibí àti tòde òní.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. Àwôn ohun-èlò iśë abínibí bí i: àdá, àkàtàýpò, ômô-owú, êmú, ôkö abbl

 2. Àwòrán çbu àti àwôn òśìśë.

10.

ÀŚÀ: ÌGBÉYÀWÓ

Àkóónú iśë

 1. ìdí tí a fi ń gbéyàwó/ lökô

 2. oríśiríśi ìgbéyàwó tí ó wà láyé àtijö àti lóde òní, ìfômôtôrô, fífë níśulökà, àśàýte, śöõśì, kóòtù, mùsùlùmí, ôkô kan aya kan, aláya púpõ abbl

d. Ìgbésê inú oríśi ìgbéyàwó kõõkan láyé àtijö

e. ìgbésê inú oríśi ìgbéyàwó kõõkan lóde òní.

ç. Àýfààní àti ìśòro inú irú ìgbéyàwó kõõkan látijö àti lóde òní.


OLÙKÖ:

 1. Śe àlàyé fún akëkõö lórí àýfààní tí ó wà nínú śíśe ìgbéyàwó

 2. Jë akëkõö jíròrò/ sô ìrírí rê;

d. kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó pêlú ìtumõ wôn

AKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí olùkö

 2. Jíròrò ní kíláásì/ sô ìrírí rç

d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Àwòrán ìgbéyàwó

 • Fídíò

 • Téèpù

 • Tçlifísàn

11.

ÈDÈ: ÒWE

i. Oríśiríśi òwe

Ìtándòwe, òwe ajçmësìn, ìrírídòwe

ii. ìwúlò òweÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríkì òwe

 2. Oríśiríśi òwe

d. Ìlò òwe/ ìwúlò òwe

OLÙKÖ:

 1. Sô ìtumõ òwe

 2. Jë kí akëkõö pa oríśiríśi òwe bí àpççrç: ìbáwí, ìkìlõ, ìmõràn abbl

d. Kô ìbêrê àwôn òwe kan sójú pátákó fún akëkõö láti parí wôn

e. Sô ìwúlò òweAKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí àlàyé olùkö

 2. Pa oríśiríśi òwe gëgë bí olùkö śe darí

d. kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. Ìwé òwe pêlú ìtumõ wôn

 2. Pátákó ìkõwé

12.

ÀŚÀ: Oyún níní, ìtöjú oyún àti ìtöjú ômô láyé àtijö àti lóde òní.

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìgbàgbö nípa ômô bíbí àti àbíkú.

b. Ohun gbogbo ló ní àsìkò, tôkô-taya ni oyún wà fún kì í śe àpön àti wúndíá.

d. Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjô; b.a òye lórí onírúurú jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó fë fëra wôn

e. Aájò láti lè tètè lóyún: àýfààní kíkó ara çni ní ìjánu nípa ìbálòpõ, yíyçra fún ìlòkulò oògùn ìsëyún abbl

ç. Bí a śe ń töjú aboyún

f. Oúnjç aśaralóore

g. Lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba)

gb. Oyún dídè

h. ÀwêbíOLÙKÖ:

a. Śàlàyé kíkún lórí ìgbàgbö Yorùbá nípa oyún níní, ìtöjú oyún àti àsìkò tó tö láti lóyún.

b. Sõrõ lórí onírúurú jënótáìpù tó wà àti ìdí tí akëkõö fi gbôdõ mô tirê.

d. La akëkõö lóye lórí jënótáìpù tó bá ara mu àti àwôn tó lè fëra wôn.

e. Kô àwôn oúnjç asaralóore tí aláboyún lè jç sójú pátákó ìkõwé.

AKËKÕÖ:

a. Jíròrò nípa àwôn tóyún wà fún

b. Sô ohun tí ó nípa oyún níní

d. Sô jënótáìpù tìrç

e. Dárúkô díê lára àwôn oúnjç aśaralóore

ç. Dárúkô díê lára àwôn õnà tí a fi ń töjú aláboyúnOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 • Àwòrán díê lára ohun èlò tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà ti ìbílê: ìkòkò àgbo, ìsáàsùn, àśèjç, ìgbàdí abbl

 • Àwòrán díê lára ohun tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà Òyìnbó.

 • Àtç tó ń fi oúnjç aśaralóore hàn.

13.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
14.

ÌDÁNWÒ

Directory: files
files -> Ucsf school of Dentistry
files -> Southern California Regional Dentistry Post-Baccalaureate Program ucla & Loma Linda, Schools of Dentistry
files -> Pursuing a career in Dentistry What's Unique about Dentistry?
files -> The university of michigan school of dentistry honor system policy for students enrolled in advanced dental education programs
files -> Curriculum vitae laurie k. Mccauley
files -> To be eligible to apply for core privileges in dentistry, the applicant must meet the following qualifications
files -> North-Western State medical University n a. I. I. Mechnikov Program for General Medicine Department
files -> National medical university of LVIV department of therapeutic dentistry
files -> An Annotated List of Websites Related to Geriatric Education for Dentists and Dental Hygienists


Share with your friends:
1   ...   21   22   23   24   25   26   27   28   ...   49


The database is protected by copyright ©dentisty.org 2019
send message

    Main page