ÕSÊ
|
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
|
ÀMÚŚE IŚË
|
1
|
ÀŚÀ: Êkö Ilé
ÀKÓÓNÚ IŚË
Oríkì êkö ilé
Ìkíni ní oríśiríśi ônà
d. Iśë ilé śíśe
e. Ìbõwõ fágbà
ç. Ìmötótó
f. Ìbömôwí abbl
|
OLÙKÖ:
sô oríkì êkö ilé
śàlàyé ní kíkún lórí oríśiríśi êkö ilé àti pàtàkì wôn láwùjô
d. śàlàyé ìkíni lóríśiríśi õnà
e. śàlàyé oríśiríśi õnà tí à ń gbà töjú ilé
ç. kô àwôn õrõ tó súyô sójú pátákó
AKËKÕÖ:
Tëtí sí àlàyé olùkö
Śe àfihàn ìkíni lóríśiríśi õnà, ìwà ômôlúàbí, ìtöjú ilé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Pátákó ìkõwé
Àwòrán
Téèpù
Tçlifísàn/ Rédíò
Fíìmù
|
2.
|
LÍTÍRÈŚÕ:
Ìwé Kíkà: Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere
ÀKÓÓNÚ IŚË
Kókó Õrõ
Àhunpõ Ìtàn
d. Ôgbön ìsõtàn
e. Ibùdó ìtàn
ç. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá
f. Lílo èdè
g. Ìjçyô àśà
gb. Àmúyç àti àléébù
|
OLÙKÖ:
jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere
śàlàyé kíkún lórí kókó àkóónú iśë bí ó ti jçyô nínú ìtàn àròsô.
ìsônísókí àhunpõ ìtàn
êdá ìtàn
ôgbön ìsõtàn
ìwúlò èdè
ìjçyô õrõ
àmúyç àti àléébù
kô àwôn õrõ tí ó súyô sí ojú pátákó
AKËKÕÖ:
a. Ka ìwé
b. Tëtí sí àlàyé olùkö
d. Kô àwôn õrõ tó súyô pêlú ìtumõ wôn
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Pátákó ìkõwé
Ìwé ìtàn àròsô tí a yàn
|
3.
|
ÈDÈ: Álífábëtì Èdè Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
Álífábëtì:
a, b, d, e, ç, f, g, gb, h, i, j, k, l, m, n, o, ô, p, r, s, ś, t, u, w, y
Köńsónáýtì:
b, d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, ś, t, w, y
d. Fáwëlì: a, e, ç, i, o, ô, u
|
OLÙKÖ:
kô álífábëtì yorùbá lápapõ sára pátáko fún akëkõö
kô àwôn lëtà tí ó dúró fún ìró köńsónáýtì àti ìró fáwëlì
d. pe wön lökõõkan fún akëkõö.
AKËKÕÖ:
fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà.
pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà bí olùkö ti pè wön
d. śe àdàkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì àti fáwëlì naa
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
kádíböõdù ńlá tí a kô álífábëtì Yorùbá sí.
kádíböõdù ńlá tí ó ń śe àfihàn àwôn ìró Köńsónáýtì àti fáwëlì lötõõtõ.
káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà náà sí.
|
4.
|
ÀŚÀ: Àwôn oúnjç ilê Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Oríkì oúnjç
b. Oríśiríśi oúnjç
d. bí a śe ń śe oúnjç kõõkan
e. ìpín sí ìsõrí àwôn oúnjç ilê Yorùbá bí i: sêmíró, ôlöràá, afáralókun, amáradán abbl
ç. ìtöjú oúnjç àjçsëkù
f. àfiwé oúnjç àtijö àti ti òde òní.
g. oúnjç tí ìlú/ agbègbè kõõkan fëràn
|
OLÙKÖ:
sô oríkì oúnjç
sô oríśìí oúnjç
d. śàlàyé bí a śe ń śe oúnjç kõõkan
e. kô àwôn oúnjç tí ó bö sí ìsõrí kan náà sára pátákó
ç. sô bí a śe ń śe ìtöjú oúnjç tí ó bá sëkù
f. sõrõ lórí àýfààní oúnjç láti oko àti ewu oúnjç inú agolo
g. Ya àtç oúnjç ti ìlú/ agbègbè kõõkan fëràn sórí pátákó.
AKËKÕÖ:
Tëtí sí àlàyé olùkö
Sô èrò tiwôn lórí oúnjç
d. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.
e. Ya àtç tí olùkö yà sójú pátákó.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Oríśìíríśìí oúnjç tútù
Àwòrán
Ohun èlò oúnjç:
Ìkòkò, epo, iyõ irú, ewébê, sítóófù abbl
|
5.
|
ÈDÈ: Sílébù èdè Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
Oríkì sílébù
Ìhun sílébù [F, KF, N]
d. pínpín õrõ sí sílébù
|
OLÙKÖ:
sô oríkì sílébù
śàlàyé ìhun sílébù
d. śe õpõlôpõ àpççrç pínpín õrõ sí sílébù sójú pátákó
AKËKÕÖ:
Tëtí sí àlàyé olùkö
Śe àpççrç pínpín õrõ sí sílébù fúnra rê
d. kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
pátákó ìkõwé
kádíböõdù tí ó śe àfihàn àwôn õrõ oní sílébù méjì, mëta abbl
|
6.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ èdè Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
Oríkì lítírèśõ
Êka lítírèśõ èdè Yorùbá
Alohùn
Àpilêkô
d. Àwôn ohun tí a lè fi dá ewì kõõkan mõ: sísun, dídá, kíkô, pípa, pípè
e. Ìlò èdè inú ewì
|
OLÙKÖ:
śe àlàyé àwôn àbùdá pàtàkì lítírèśõ
śe àfiwé lítírèśõ àpilêkô àti alohùn
kô àpççrç lítírèśõ àpilêkô fún àwôn akëkõö.
śàlàyé àwôn ìsõrí mëtêêta lítírèśõ àpilêkõ láti fi ìyàtõ wön hàn.
sô àpççrç õkõõkan àwôn ìsõrí náà fún akëkõö.
AKËKÕÖ:
Tëtí sí gbogbo àlàyé olùkö dáradára
Ya àtç láti fi ìyàtõ lítírèśõ àpilêkô àti alohùn hàn.
kô àpççrç mìíràn fún ìsõrí kõõkan lítírèśõ àpilêkô.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Ìwé oríśiríśi
Lítírèśõ àpilêkô: eré-oníśe, ewì àti ìtàn àròsô
|
7.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Ìtúpalê ewì alohùn (Àsàyàn ìwé kan)
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àkóónú
kókó õrõ àśà tó súyô
ìhun
lílé/ gbígbè, àdákô, àjùmõkô
ìlò èdè: ônà èdè àti ìsôwölo-èdè
ìjçyô àśà
b. Lítírèśõ alohùn mìíràn
d. õgangan ipò àwôn akéwì: êśìn wön/ ìśe wôn, àkókò ìkéwì abbl
|
OLÙKÖ:
jë kí akëkõö ka ewì alohùn löpõlöpõ ìgbà
śe àlàyé lórí kókó õrõ êkö, ìlò èdè, àmúyç àti àléébù inú ìwé àsàyàn ewì alohùn.
AKËKÕÖ:
fi etí sí ewì tí olùkö ń kà fún wôn.
Gbìyànjú láti kéwì tí ó bá mõ
d. ka ìwé àsàyàn yìí
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Ìwé tó jçmö ewì alohùn
Àwòrán tó bá ewì yìí mu
Pátákó ìkõwé
|
8.
|
ÌHUN ÕRÕ:
a. Möfíìmù ní èdè Yorùbá
b. Õnà tí a ń gbà śêdá õrõ-orúkô
ÀKÓÓNÚ IŚË
oríkì möfíìmù
ìśêdá õrõ-orúkô –àfòmö ìbêrê (a-, on-, o, oní-, àì-, àti-, àfòmö àárin àpètúnpè (kíkún, çlëbç)
|
OLÙKÖ:
Śàlàyé oríśìí ìhun õrõ
Śàlàyé ìśêdá àwôn õrõ
d. Kô õpõlôpõ àpççrç oríśiríśi õrõ sórí pátákó.
AKËKÕÖ:
Sô oríśiríśi ìhun õrõ
Sô bí a śe śêdá àwôn õrõ
d. Da õrõ-orúkô ìśêdá tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Śe àlàyé ìlò àfòmö ìbêrê onísílébù méjì láti śêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.
Kô õrõ ìpìlê mëta sílê
d. Kô àpççrç õrõ ìśêdá alápètúnpè kíkún mëta àti alápètúnpè çlëbç
|
9.
|
IŚË ABÍNIBÍ
i. Onírúurú iśë ilê Yorùbá bí i àgbê, alágbêdç, onídìrí, aśô híhun, aró dídá, awakõ abbl
ii. Ìkíni àti ìdáhùn fún onírúurú iśë.
ÀKÓÓNÚ IŚË
oríkì iśë abínibí àti àpççrç iśë: àgbê, ôdç, aśô híhun, aró dídá, epo fífõ, irun dídì, àyàn, olóólà, alágbêdç
Bí a ti ń kö iśë
d. ìwúlò iśë kíkö
e. iśë ôkùnrin, obìnrin, tôkùnrin-tobìnrin ní àtijö àti lóde òní.
|
OLÙKÖ:
Sô oríkì àti ohun tí iśë abínibí jë
Tö akëkõö sönà láti mô pàtàkì iśë śíśe àti bí a śe ń kö iśë kõõkan.
d. Sô àýfààní iśë kíkö
e. Kô ìjôra àti ìyàtõ tó wà nínú iśë abínibí àti tòde òní sójú pátákó
AKËKÕÖ:
Sô ohun tí o mõ nípa iśë śíśe àti ìdí tí ó fi yç kí ènìyàn śiśë
Kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé rç.
d. Śe àfiwé iśë abínibí àti tòde òní.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Àwôn ohun-èlò iśë abínibí bí i: àdá, àkàtàýpò, ômô-owú, êmú, ôkö abbl
Àwòrán çbu àti àwôn òśìśë.
|
10.
|
ÀŚÀ: ÌGBÉYÀWÓ
Àkóónú iśë
ìdí tí a fi ń gbéyàwó/ lökô
oríśiríśi ìgbéyàwó tí ó wà láyé àtijö àti lóde òní, ìfômôtôrô, fífë níśulökà, àśàýte, śöõśì, kóòtù, mùsùlùmí, ôkô kan aya kan, aláya púpõ abbl
d. Ìgbésê inú oríśi ìgbéyàwó kõõkan láyé àtijö
e. ìgbésê inú oríśi ìgbéyàwó kõõkan lóde òní.
ç. Àýfààní àti ìśòro inú irú ìgbéyàwó kõõkan látijö àti lóde òní.
|
OLÙKÖ:
Śe àlàyé fún akëkõö lórí àýfààní tí ó wà nínú śíśe ìgbéyàwó
Jë akëkõö jíròrò/ sô ìrírí rê;
d. kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó pêlú ìtumõ wôn
AKËKÕÖ:
Tëtí sí olùkö
Jíròrò ní kíláásì/ sô ìrírí rç
d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Àwòrán ìgbéyàwó
Fídíò
Téèpù
Tçlifísàn
|
11.
|
ÈDÈ: ÒWE
i. Oríśiríśi òwe
Ìtándòwe, òwe ajçmësìn, ìrírídòwe
ii. ìwúlò òwe
ÀKÓÓNÚ IŚË
Oríkì òwe
Oríśiríśi òwe
d. Ìlò òwe/ ìwúlò òwe
|
OLÙKÖ:
Sô ìtumõ òwe
Jë kí akëkõö pa oríśiríśi òwe bí àpççrç: ìbáwí, ìkìlõ, ìmõràn abbl
d. Kô ìbêrê àwôn òwe kan sójú pátákó fún akëkõö láti parí wôn
e. Sô ìwúlò òwe
AKËKÕÖ:
Tëtí sí àlàyé olùkö
Pa oríśiríśi òwe gëgë bí olùkö śe darí
d. kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Ìwé òwe pêlú ìtumõ wôn
Pátákó ìkõwé
|
12.
|
ÀŚÀ: Oyún níní, ìtöjú oyún àti ìtöjú ômô láyé àtijö àti lóde òní.
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìgbàgbö nípa ômô bíbí àti àbíkú.
b. Ohun gbogbo ló ní àsìkò, tôkô-taya ni oyún wà fún kì í śe àpön àti wúndíá.
d. Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjô; b.a òye lórí onírúurú jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó fë fëra wôn
e. Aájò láti lè tètè lóyún: àýfààní kíkó ara çni ní ìjánu nípa ìbálòpõ, yíyçra fún ìlòkulò oògùn ìsëyún abbl
ç. Bí a śe ń töjú aboyún
f. Oúnjç aśaralóore
g. Lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba)
gb. Oyún dídè
h. Àwêbí
|
OLÙKÖ:
a. Śàlàyé kíkún lórí ìgbàgbö Yorùbá nípa oyún níní, ìtöjú oyún àti àsìkò tó tö láti lóyún.
b. Sõrõ lórí onírúurú jënótáìpù tó wà àti ìdí tí akëkõö fi gbôdõ mô tirê.
d. La akëkõö lóye lórí jënótáìpù tó bá ara mu àti àwôn tó lè fëra wôn.
e. Kô àwôn oúnjç asaralóore tí aláboyún lè jç sójú pátákó ìkõwé.
AKËKÕÖ:
a. Jíròrò nípa àwôn tóyún wà fún
b. Sô ohun tí ó nípa oyún níní
d. Sô jënótáìpù tìrç
e. Dárúkô díê lára àwôn oúnjç aśaralóore
ç. Dárúkô díê lára àwôn õnà tí a fi ń töjú aláboyún
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Àwòrán díê lára ohun èlò tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà ti ìbílê: ìkòkò àgbo, ìsáàsùn, àśèjç, ìgbàdí abbl
Àwòrán díê lára ohun tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà Òyìnbó.
Àtç tó ń fi oúnjç aśaralóore hàn.
|
13.
|
ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
|
|
14.
|
ÌDÁNWÒ
|
|